Competition in this pair is now closed. Discussion and feedback about the competition in this language pair may now be provided by visiting the "Discussion & feedback" page for this pair. Entries may also be individually discussed by clicking the "Discuss" link next to any listed entry. Source text in English Who cast that first fateful tomato that started the La Tomatina revolution? The reality is no one knows. Maybe it was an anti-Franco rebellion, or a carnival that got out of hand. According to the most popular version of the story, during the 1945 festival of Los Gigantes (a giant paper mĂąchĂ© puppet parade), locals were looking to stage a brawl to get some attention. They happened upon a vegetable cart nearby and started hurling ripe tomatoes. Innocent onlookers got involved until the scene escalated into a massive melee of flying fruit. The instigators had to repay the tomato vendors, but that didn't stop the recurrence of more tomato fightsâand the birth of a new tradition.
Fearful of an unruly escalation, authorities enacted, relaxed, and then reinstated a series of bans in the 1950s. In 1951, locals who defied the law were imprisoned until public outcry called for their release. The most famous effrontery to the tomato bans happened in 1957 when proponents held a mock tomato funeral complete with a coffin and procession. After 1957, the local government decided to roll with the punches, set a few rules in place, and embraced the wacky tradition.
Though the tomatoes take center stage, a week of festivities lead up to the final showdown. It's a celebration of Buñol's patron saints, the Virgin Mary and St. Louis Bertrand, with street parades, music, and fireworks in joyous Spanish fashion. To build up your strength for the impending brawl, an epic paella is served on the eve of the battle, showcasing an iconic Valencian dish of rice, seafood, saffron, and olive oil.
Today, this unfettered festival has some measure of order. Organizers have gone so far as to cultivate a special variety of unpalatable tomatoes just for the annual event. Festivities kick off around 10 a.m. when participants race to grab a ham fixed atop a greasy pole. Onlookers hose the scramblers with water while singing and dancing in the streets. When the church bell strikes noon, trucks packed with tomatoes roll into town, while chants of "To-ma-te, to-ma-te!" reach a crescendo.
Then, with the firing of a water cannon, the main event begins. That's the green light for crushing and launching tomatoes in all-out attacks against fellow participants. Long distance tomato lobbers, point-blank assassins, and medium range hook shots. Whatever your technique, by the time it's over, you will look (and feel) quite different. Nearly an hour later, tomato-soaked bombers are left to play in a sea of squishy street salsa with little left resembling a tomato to be found. A second cannon shot signals the end of the battle. | Winning entries could not be determined in this language pair.There were 6 entries submitted in this pair during the submission phase. Not enough votes were submitted by peers for a winning entry to be determined.
Competition in this pair is now closed. | Tani Ăł ju tĂČmĂĄtĂŹ Ă ká»Ìká»Ì nĂĄĂ tĂ Ăł mĂș kĂ rĂČgbĂČdĂŹyĂ n La Tomatina báșčÌráșčÌ? ĂtĂtá»Ì ibáșčÌ ni pĂ© kĂČ sĂ áșčnitĂ Ăł má»Ì. BĂłyĂĄ ĂŹáčŁá»ÌtáșčÌ ĂŹáčŁĂČdĂŹ Faranse ni, tĂ bĂ Ă já»ÌdĂșn kan tĂ kĂČ áčŁe Ă© áčŁĂ kĂłso má»Ì. GáșčÌgáșčÌ bĂ Ă lĂ yĂ© tĂ Ăł wá»Ìpá»Ì jĂčlá» nĂpa ĂŹtĂ n nĂĄĂ , lĂĄsĂŹkĂČ ayáșčyáșč Los Gigantes nĂ á»dĂșn 1945 (ĂŹwá»Ìde Ă wá»n Ăšre nlĂĄ tĂ a fi amá»Ì onĂ-pĂ©pĂ áčŁe), Ă wá»n ara ĂŹlĂș nwĂĄ á»ÌnĂ lĂĄti dĂĄ ĂŹjĂ sĂláșčÌ kĂ Ă wá»n ĂšnĂŹyĂ n lĂš áčŁĂ kĂyĂšsi wá»n. Wá»Ìn rĂ á»má»lanke kan tĂ Ăł kĂł orĂáčŁirĂáčŁi ewĂ©báșčÌ Ă ti Ăšso nĂtĂČsĂ wá»n lĂłjijĂŹ, wá»Ìn sĂŹ báșčÌráșčÌ sĂĂ nĂ ju Ă wá»n tĂČmĂĄtĂŹ tĂł ti pá»Ìn nĂnĂș ráșčÌ nĂč. Ăwá»n ĂČwĂČran tĂ kĂČ má» ohun tĂ nlá» nĂĄĂ darapá»Ì má»Ì wá»n, tĂtĂ tĂ ibi ĂŹáčŁáșčÌláșčÌ nĂĄĂ fi di ibi ĂŹdĂ rĂșdĂ pá»Ì Ă wá»n Ăšso tĂ nfĂČ kiri. Ăwá»n á»ÌdĂĄdĂĄ nĂĄĂ nĂ lĂĄti san Ă sanpadĂ fĂșn Ă wá»n tĂł ni tĂČmĂĄtĂŹ nĂĄĂ , áčŁĂčgbá»Ìn ĂšyĂ kĂČ dĂĄ wĂwĂĄyĂ© Ă wá»n ĂŹjĂ tĂČmĂĄtĂŹ nĂĄĂ nĂgbĂ mĂŹĂrĂ n dĂșrĂł âĂ ti ĂŹbáșčÌráșčÌ Ă áčŁĂ titun. NĂtorĂ ĂŹbáșčÌrĂč pĂ© kĂ ĂŹjĂ nĂĄĂ mĂĄ di ti ĂŹgboro, Ă wá»n alĂĄáčŁáșč ĂŹlĂș gbĂ© Ă wá»n orĂáčŁirĂáčŁi ĂČfin tĂł de Ă wá»n ĂšnĂŹyĂ n má»ÌláșčÌ jĂĄde ni Ă wá»n á»dĂșn 1950, wá»Ìn dáșč Ă wá»n ĂČfin nĂĄĂ nĂláșčÌ dĂáșčÌ, wá»Ìn sĂŹ tĂșn mĂș wá»n le sĂi. NĂ á»dĂșn 1951, Ă wá»n ara ĂŹlĂș tĂ Ăł tĂ pĂĄ sĂ ĂČfin nĂĄĂ ni a tĂŹ má»ÌlĂ© tĂtĂ di ĂŹgbĂ tĂ ariwo Ă wá»n ara ĂŹlĂș bÚÚrĂš fĂșn ĂŹtĂșsĂláșčÌ wá»n. ĂfojĂșdi tĂ Ăł lĂłkĂŹkĂ jĂčlá» sĂ awá»n ĂČfin tĂł de ni má»ÌláșčÌ nĂpa á»Ìrá»Ì tĂČmĂĄtĂŹ nĂĄĂ ni Ăł wĂĄyĂ© á»dĂșn 1957 nĂgbĂ tĂ Ă wá»n kan áčŁe ĂŹsĂŹnkĂș yáșčÌyáșčÌ fĂșn tĂČmĂĄtĂŹ páșčÌlĂș pĂłsĂ Ă ti Ă pĂ©já» Ă wá»n ĂšnĂŹyĂ n. LáșčÌyĂŹn á»dĂșn 1957, ĂŹjá»ba ĂŹbĂláșčÌ pinnu lĂĄti da ara wá»n pá»Ì má»Ì ohun tĂ n áčŁáșčláșčÌ, gbĂ© Ă wá»n ĂČfin melo kan jĂĄde, kĂ wá»Ìn sĂŹ táșčÌwá»Ìgba Ă áčŁĂ apaniláșčÌáșčÌrĂn nĂĄĂ . BĂ Ăł tiláșčÌ jáșčÌ pĂ© Ă wá»n tĂČmĂĄtĂŹ nĂĄĂ ni Ăł wá»Ìpá»Ì jĂč, ayáșčyáșč lá» fĂșn odindin á»ÌsáșčÌ kan tĂtĂ di ĂŹgbĂ ĂŹjĂ kadĂŹ ĂŹkáșčyĂŹn. Ă jáșčÌ Ă kĂłkĂČ ayáșčyáșč Ă wá»n baba ĂŹsĂ láșčÌ Ă wá»n áșčni mĂmá»Ì Buñol, Maria WĂșndĂĂĄ Ă ti ti St. Louis Bertrand, páșčÌlĂș ĂŹwá»Ìde ojĂș pĂłpĂł, orin Ă ti Ă wá»n ohun ĂŹáčŁerĂ© tĂ n tannĂĄ gáșčÌgáșčÌ bĂ Ă áčŁĂ ĂŹdĂčnnĂș Ă wá»n ara SĂpĂ©ĂšnĂŹ. LĂĄti fi agbĂĄra kĂșn ara áșčni nĂ ĂŹmĂșrasĂláșčÌ ĂŹjĂ kadĂŹ tĂ mbá»Ì lá»ÌnĂ , a mĂĄ a n se ĂŹráșčsĂŹ pĂ tĂ kĂŹ kan páșčÌlĂș adĂŹáșč Ă ti Ă wá»n oĂșnjáșč tĂ Ă nrĂ lĂĄti inĂș omi bĂi áșčja, Ă ti báșčÌáșčÌbáșčÌáșčÌ lá», nĂ aláșčÌ á»já»Ì tĂ Ăł áčŁĂĄĂĄjĂș ĂŹjĂ kadĂŹ nĂĄĂ , ĂšyĂ tĂ n áčŁĂ fihĂ n oĂșnjáșč aká»ni Ă wá»n ara Valencia páșčÌlĂș ĂŹráșčsĂŹ, Ă wá»n orĂáčŁirĂáčŁi oĂșnjáșč tĂ a n rĂ lĂĄti inĂș omi, ĂšrĂČjĂ oĂșnjáșč tĂ a n pĂ© nĂ saffron,Ă ti ĂČrĂłrĂł ĂłlĂfĂŹ. LĂłnĂŹĂ, ayáșčyáșč alĂĄĂŹnĂ ĂŹhĂĄmá»Ì yĂŹĂ ti nĂ ĂŹlĂ nĂ ĂštĂČ dĂáșčÌ sĂi. Ăwá»n olĂčáčŁĂštĂČ ti táșčÌsĂwĂĄjĂș dĂ© ibi pĂ© wá»n a mĂĄ a gbin orĂáčŁi tĂČmĂĄtĂŹ tĂ kĂČ dĂčn rĂĄrĂĄ kan fĂșn ayáșčyáșč á»lá»Ìdá»á»dĂșn nĂĄĂ . Ayáșčyáșč a mĂĄ a báșčÌráșčÌ nĂ agogo máșčÌáșčÌwĂĄ ĂČwĂșrá»Ì, nĂgbĂ tĂ Ă wá»n olĂčkĂłpa a mĂĄ a sĂșrĂ© lá» lĂĄti lá» gbĂĄ áșčran áșčláșčÌdáșčÌ tĂ a so má»Ì ĂČkĂš ĂČpĂł elĂ©po lĂĄra kan mĂș. Ăwá»n ĂČwĂČran a mĂĄ a lo okĂșn onĂhĂČ tĂ a fi nfa omi lĂĄti fi fĂșn omi sĂ Ă wá»n ajĂŹfĂ nĂĄĂ lĂĄra bĂ wá»Ìn ti nká»rin, tĂ wá»Ìn sĂŹ njĂł nĂ ojĂș ĂČpĂłpĂł. NĂgbĂ tĂ aago ilĂ© ĂŹjá»ÌsĂŹn bĂĄ lu mejila á»ÌsĂĄn, Ă wá»n á»ká»Ì akáșčÌrĂč tĂ Ăł kĂșn fĂșn tĂČmĂĄtĂŹ yĂłĂČ yĂ wá»lĂ© sĂnĂș ĂŹlĂș, nĂgbĂ tĂ ariwo "To-ma-te, to-ma-te!" yĂłĂČ wĂĄ gba gbogbo ĂČde kan. NĂgbĂ nĂĄĂ , nĂpasáșčÌ omi fĂfá»Ìn kiri lĂĄti inĂș ĂŹgĂČ, ĂŹáčŁáșčÌláșčÌ nĂĄĂ gan-an-gan yĂłĂČ wĂĄ báșčÌráșčÌ. ĂĂ mĂŹ ĂŹtáșčÌsĂwĂĄjĂș ni ĂšyĂ fĂșn fĂfá»Ì sĂ wáșčÌwáșčÌ Ă ti jĂju tĂČmĂĄtĂŹ kĂĄĂ kiri nĂnĂș ĂŹdojĂș ĂŹjĂ ká» Ă wá»n áșčláșčgbáșčÌ olĂčkĂłpa. Ăwá»n ĂšnĂŹyĂ n tĂ Ăł má» tĂČmĂĄtĂŹ jĂč lĂĄti á»ÌnĂ jĂjĂŹn, Ă wá»n ĂČgbĂłjĂș apĂ nĂŹyĂ n, Ă ti Ă wá»n tĂł má»Ì á»Ì jĂč lĂĄti ĂŹtĂČsĂ yĂłĂČ báșčÌráșčÌ sĂ nĂ sá» á»Ì lĂłkĂČ. OrĂáčŁi á»ÌnĂ yĂČĂłwĂč tĂ ĂŹwá» bĂĄ má»Ì á»Ì lĂČ, nĂgbĂ tĂ ohun gbogbo yĂłĂČ bĂĄ fi parĂ, ĂŹwá» kĂŹ yĂłĂČ jáșčÌ ara ráșč má»Ì. BĂi wĂĄkĂ tĂ kan láșčÌyĂŹn nĂĄĂ , a Ăł fi Ă wá»n tĂł má» tĂČmĂĄtĂŹ jĂč bĂi Ă dĂł olĂłrĂł sáșčÌyĂŹn lĂĄti mĂĄ a gbĂ© áșčsáșčÌ ijĂł lá»Ìká»Ìá»Ìkan lĂĄĂ ĂĄrĂn á»báșčÌ tĂ kĂČ sĂ ohun tĂ Ăł fi já» á»báșčÌ tĂČmĂĄtĂŹ má»Ì. Omi fĂfá»Ìn kĂĄĂ kiri áșčláșčÌáșčÌkejĂŹ ni Ăł jáșčÌ Ă Ă mĂŹ ĂČpin ĂŹjĂ kadĂŹ nĂĄĂ . | Entry #21884 — Discuss 0 — Variant: Not specifiednone
Voting points | 1st | 2nd | 3rd |
---|
20 | 3 x4 | 3 x2 | 2 x1 |
- 1 user entered 5 "dislike" tags
- 1 user agreed with "dislikes" (1 total agree)
- 1 user disagreed with "dislikes" (3 total disagrees)
-1 1 La Tomatina | Mistranslations "La Tomatina" can still be translated into Yoruba. "La" is an article in Spanish language meaning "The" in English and "Naa" in Yoruba language, and "Tomatina" can be translated as "Tomati" or Tomato" in Yoruba Language. | eltee | |
+1 1 wĂĄyĂ© á»dĂșn | Omission Omssion of preposition "ni" between "waye" and "odun" | eltee | |
-1 1 LáșčÌyĂŹn á»dĂșn 1957, ĂŹjá»ba ĂŹbĂláșčÌ pinnu lĂĄti da ara wá»n pá»Ì má»Ì ohun tĂ n áčŁáșčláșčÌ, gbĂ© Ă wá»n ĂČfin melo kan jĂĄde | Omission There is omission of 3rd person phrasal pronoun "won si" in between "sele," and "gbe", so the statement should read "Leyin odun 1957, ĂŹjá»ba ĂŹbĂláșčÌ pinnu lĂĄti da ara wá»n pá»Ì má»Ì ohun tĂ n áčŁáșčláșčÌ, won si gbĂ© Ă wá»n ĂČfin melo kan jĂĄde" | eltee | |
kĂ | Grammar errors The use of modal verb "Ki" here is irrelevant and incorrect. The right word here should be "bakannaa" or "ni afikun" | eltee No agrees/disagrees | |
-1 1 nĂpasáșčÌ omi fĂfá»Ìn kiri lĂĄti inĂș ĂŹgĂČ | Mistranslations Th word "cannon" is not translated as "igo" but as "ibon nla" | eltee | |
| Tani o ká»ká» ju tomati aká»ká» naa ti da iáčŁá»táșč La Tomatina siláșč? Otitá» ibáșč ni wipe ko si áșčni ti o má». Boya iáčŁá»táșč alodi si ijá»ba Faranse tabi ayáșčyáșč idaraya ti o ká»ja Ă Ă lĂ ni. Gáșčge bii áșčya itan ti o wá»pá» julá», ni igba ayáșčyáșč ti Los Gigantisi (tito awá»n Ăšre nla ti a fi pĂ©pĂ áčŁe ká»ja) ti á»dun 1945, awá»n ara adugbo nfáșč áčŁeto ija kan lati pe awá»n eniyan sá»dá» wá»n. Ni wá»n ba kan á»má»lanke ewebáșč kan ni ará»wá»to ti wá»n si báșčráșč si ni sá» awá»n tomati ti o ti pá»n. Awá»n oluworan ti ko má» nkankan ba da sii titi ti iran naa fi di ija-igboro nla ti eso to nfo. Awá»n ti o fĂ ĂĄ ni lati san owĂł fun awá»n ti o nta tomati naa, áčŁugbá»n eyi ko da wiwaye awá»n ija tomati duroâati ĂŹbĂ aáčŁa atá»wodá» titun kan. Awá»n alaáčŁáșč, ni ibáșčru iwa ti wá»n ko ni le kapa, áčŁe ofin, wá»n tun ráșč á»wá» ofin naa siláșč, nigba ti o ya wá»n tun mupada sipo awá»n ofin ti o dÚé láșčsáșčsáșč ni awá»n á»dun 1950. Ni á»dun 1951, awá»n ara adugbo ti o tapa si ofin ni wá»n timá»le titi ti igbe awá»n ara ilu fi pĂš fun itusiláșč wá»n. Itapa si fifi ofin de tomati ti o lokiki julá» áčŁáșčláșč ni á»dun 1957 nigbati awá»n olufilá»láșč áčŁe isinku áșčgan tomati kan páșčlu posi ati iwá»de. Láșčyin á»dun 1957, ijá»ba ibiláșč pinnu lati ba igba mu, wá»n fi awá»n ofin kan leláșč, ti wá»n si faramá» aáčŁa atá»wá»dá»wá» adáșčrin pani naa. Bi o tiláșč jáșč wipe tomati ni o gbajumá» julá», awá»n ayáșčyáșč á»lá»sáșč kan maa nwaye áčŁaaju asekagba yi. O jáșč ajá»yá» ti awá»n eniyan mimá» alatiláșčyin Buñol, Wundia Maria ati St Louis Bertrand, páșčlu iwá»de ni opopona, orin, ati fifi ina-mĂšremĂšre dara páșčlu ayá» ni aáčŁa SpaniáčŁi. Lati mu agbara ráșč le fun ija igboro to nbá», ounjáșč atijá» ti spaniáčŁi ni wá»n maa njáșč ni aláșč ti o áčŁaaju ija naa, eyiti o nfi iráșčsi ti o gbajumá» ti FalenáčŁia, ohun jijáșč lati inu okun, ĂŹtĂ nnĂĄ safurá»nu, ati ororo olifi han. Loni, ayáșčyáșč alaini idiwá» yii ti ni awá»n odiwá»n ĂštĂČ. Awá»n oluáčŁeto ti táșčsiwaju de bii wipe wá»n gbin iru awá»n tomati kan ti ko áčŁe e jáșč fun iáčŁáșčláșč á»dá»á»dun naa. Ajá»dun maa nbáșčre ni bi aago máșčwa owurá» (10 a.m) nigbati awá»n olukopa ba sare lati lá» gba áșčran áșčláșčda ti a ti yan ti o wa loke opo ti ti fi girisi yi mu. Awá»n oluworan yoo maa tu omi si awá»n ti o nwá» kiri naa lara ni bi wá»n áčŁe nká»rin ti wá»n si njo ni awá»n opopona. Ni igbati ti aago áčŁá»á»áčŁi ba dun ni á»san gan-gan, awá»n á»ká» ti a ti di tomati si yoo wá»lu, nigbati ariwo "Tomati, tomato!" yoo ta. Nigbanaa, páșčlu yinyin ibá»n olomi, iáčŁáșčláșč gan-gan yoo báșčráșč. Eyi ni imá»láșč atá»ka fun rĂrĂșn ati jĂju awá»n tomati ni gbogbo á»na lati dojuká» awá»n olukopa miiran. Awá»n ti o le ju tomati lá» jinna rere, awá»n asun má»ni pani, ati awá»n jiju ti ko jinna ju. Eyikeyi ti o jáșč á»na tiráșč, ni igba ti o ba pari, iwá» yoo da (ti iwá» yoo si ni imá»lara) yatá». Ni bii wakati láșčyin naa, awá»n alado adugbamu ti tomati ti rin ni a o fi siláșč lati áčŁere ninu okun opopona páșčlu tomati diáșč to sáșčku lati wĂĄ rĂ. Ibá»n yinyin eláșčáșčkeji yoo fi aami opin ija naa han. | Entry #19372 — Discuss 0 — Variant: Not specifiednone
Voting points | 1st | 2nd | 3rd |
---|
17 | 3 x4 | 2 x2 | 1 x1 |
- 2 users entered 6 "dislike" tags
- 2 users agreed with "dislikes" (3 total agrees)
| Omission there is omission of a word "o" between "ti" and "da". It should be written as "ti o da". | eltee | |
+1 Gáșčge bii áșčya itan ti o wá»pá» julá», ni igba ayáșčyáșč ti Los Gigantisi (tito awá»n Ăšre nla ti a fi pĂ©pĂ áčŁe ká»ja) ti á»dun 1945, awá»n ara adugbo nfáșč áčŁeto ija kan lati pe awá»n eniyan sá»dá» wá»n | Other There are no accents on the whole of the text. | eltee | |
mupada sipo awá»n ofin ti o dÚé láșčsáșčsáșč | Spelling The word order here is incorrect. It should read "wá»n tĂșn mĂș Ă wá»n ĂČfin nĂĄĂ padĂ sĂpĂČ" | Olayemi Olabenjo No agrees/disagrees | |
ti ti fi girisi yi | Mistranslations This is not making any meaning. | Olayemi Olabenjo No agrees/disagrees | |
Ni bii wakati láșčyin naa | Omission It should read Ni bii wakati kan leyin naa. | Olayemi Olabenjo No agrees/disagrees | |
| Tani o juÌ tomato maÌlegbaÌgbeÌ aÌká»Ìká»Ì yáșčn toÌ báșčÌráșčÌ roÌgboÌdiÌyaÌn La Tomatina naÌaÌ. OÌtiÌtá»Ì ibáșčÌ ni peÌ koÌ siÌ áșčni tiÌ o má»Ì. BoÌyaÌ iÌáčŁá»ÌtáșčÌ iÌloÌdiÌsiÌ-Franko kan ni, tabi ayáșčyáșč-ojuÌ-poÌpoÌ kan tiÌ oÌ bá»Ìwá»Ì soÌriÌ ni. GáșčÌgáșčÌ biÌ áșčÌyaÌ-iÌtaÌn naÌaÌ kan toÌ wá»Ìpá»Ì julá», niÌ aÌkoÌkoÌ aÌjá»ÌduÌn Los Gigantes ti á»dun 1945 (tiÌ oÌ maÌa n waÌyeÌ niÌpa riÌru oÌmiÌraÌn á»má»-laÌ-n-gidi kan tiÌ a fi áșčrá»Ìfá»Ì beÌbaÌ áčŁe kaÌaÌkiri), tiÌ aÌwá»n á»má» oniÌláșčÌ kan n wá»ÌnaÌ lati áčŁe jaÌgiÌdiÌjaÌgan kan kiÌ araÌyeÌ leÌ ba aÌ táșčÌtiÌ siÌ áșčÌhoÌnuÌ wá»n. N áčŁe ni wá»n áčŁeÌeÌáčŁiÌ áčŁe alaÌbaÌaÌpaÌdeÌ á»má»lanke áșčláșčÌfá»Ìá»Ì kan niÌtoÌsi, tiÌ wá»n siÌ báșčÌáșčÌráșčÌ siÌ niÌ sá» tomato piÌpá»Ìn lu ara wá»n. Awá»n tiÌ n woÌran jáșčÌjáșčÌ páșčÌluÌ nkoÌ má»Ì igbaÌ tiÌ wá»n darapá»Ì má»Ì wá»n tiÌtiÌ tiÌ gbogbo ráșčÌ fi di iáčŁu-ata-yaÌn-an-yan-an nla tiÌ eÌáčŁo tiÌ n foÌ fiÌriÌ kiri niÌnuÌ afáșčÌfáșčÌ. AÌwá»n adaÌruÌguÌduÌ siÌláșčÌ á»já»Ì naÌaÌ niÌ lati sanwo fuÌn aÌwá»n oniÌtomati á»ÌhuÌn, suÌgbá»Ìn eÌyiÌ koÌ kuÌkuÌ dáșčÌkun peÌ kiÌ iÌjaÌ oniÌtoÌmaÌtiÌ ma tuÌn áčŁe alaÌiÌ-waÌyeÌ má»Ì â eÌyiÌ ni biÌ iÌáčŁáșčÌdaÌláșčÌ tuntun kan tuÌn áčŁe daÌyeÌ. PáșčÌluÌ iÌbáșčÌruÌbojo peÌ fiÌtiÌnaÌ leÌ waÌyeÌ, ni iÌjá»Ìba ba áčŁoÌfin, laÌti diÌn jaÌgiÌdiÌ-jaÌgan aÌjá»ÌduÌn yiÌiÌ kuÌ, ni wá»n baÌ áčŁaÌgbeÌkaláșčÌ oniÌruÌuruÌ oÌfin laÌaÌrin á»duÌn 1950 laÌti gbáșčÌsáșčÌ leÌ aÌjá»ÌduÌn yiÌiÌ. NiÌ á»duÌn 1951, aÌwá»n á»má»-oniÌláșčÌ ti wá»n ruÌfin yiÌiÌ ni wá»n juÌ siÌ aÌtiÌmá»ÌleÌ tiÌtiÌ diÌ iÌgbaÌ tiÌ gbogbo iÌluÌ pariwo leÌ iÌjá»ba loÌriÌ laÌti daÌ wá»n siÌláșčÌ. IÌtaÌpaÌ siÌ oÌfin gbiÌgbáșčÌsáșčÌ leÌ aÌjá»ÌduÌn tomati tiÌ oÌ gbajuÌgbajaÌ juÌlá» waÌyeÌ niÌ á»duÌn 1957 niÌgbaÌ tiÌ aÌwá»n tiÌ wá»n faramá»Ì aÌjá»ÌduÌn yiÌiÌ áčŁe iÌsiÌnkuÌ alaÌwaÌdaÌ kan fuÌn tomati páșčÌluÌ poÌsiÌ aÌti iÌwá»Ìde. LáșčÌyiÌn á»duÌn 1957, ni iÌjá»ba iÌbiÌláșčÌ baÌ gbaÌ lati páșčÌluÌ á»bá» jáșčko wá»n, wá»n gbeÌ aÌwá»áč
iÌlaÌnaÌ kan kaláșčÌ, wá»n siÌ fá»wá»ÌsiÌ iÌáčŁáșčÌdaÌláșčÌ jaÌkujaÌku naÌaÌ. BiÌ o tiláșčÌ jáșčÌ peÌ tomato ni oÌ ni aÌjá»ÌduÌn yiÌiÌ, aÌáčŁeyáșč á»lá»ÌáčŁáșčÌ kan yoÌoÌ áčŁaaÌjuÌ aÌáčŁekaÌgbaÌ aÌjá»ÌduÌn naÌaÌ. BiÌ iÌ áčŁiÌáčŁe aÌyaÌjá» aÌwá»n áșčni miÌmá»Ì iÌluÌ Buñol, ti Maria Wundia aÌti ti áșžni-MiÌmá»Ì Louis Bertrand, páșčÌluÌ aÌwá»n iÌwá»Ìde ojuÌ-poÌpoÌ, torin-tiÌluÌ, aÌti yiÌnyin biÌsiÌkoÌ niÌ biÌ aÌwá»n ara iláșčÌ Spain ti maÌa n áčŁe. LaÌti gba agbaÌra siláșč de giÌdiÌgboÌ tiÌ n bá»Ì lá»ÌnaÌ, wá»n yoÌoÌ bu ouÌnjáșč paella baÌ-n-taÌ-baÌn-taÌ fun oluÌkuÌlukuÌ niÌ aÌiÌsuÌn á»já»Ì iÌjaÌduÌ naÌaÌ, eÌyiÌ tiÌ iÌ áčŁáșč aÌwá»n ounjáșč aÌdaÌyeÌbaÌ biÌ iÌráșčsiÌ, áșčran-oÌun-áșčja-odoÌ, iÌyáșčÌfun safuroni aÌti oÌroÌroÌ oÌliÌfiÌ. Lá»Ìjá» oÌniÌ, aÌjá»ÌduÌn koÌ-loÌkuÌn-lá»ÌruÌn yiÌiÌ ti ni iÌjaÌnu diÌáșčÌdiÌáșčÌ baÌyiÌiÌ. AÌwá»n alaÌaÌtoÌ-aÌjá»ÌduÌn ti áčŁe eÌ deÌbi peÌ kiÌ wá»n lá» waÌ oniÌruÌuruÌ aÌwá»n áșčÌsaÌ tomati niÌ tiÌtoriÌ aÌyáșčyáșč á»lá»Ìdá»á»duÌn naÌaÌ. AÌjá»ÌduÌn maÌa n báșčÌráșčÌ niÌ aago máșčÌwaÌaÌ aÌaÌrá»Ì niÌgbaÌtiÌ aÌwá»n oluÌkoÌpa yoÌoÌ saÌreÌ laÌti re ekiÌriÌ áșčran kan tiÌ a so má»Ì oriÌ oÌpoÌ kan tiÌ n yá»Ì bá»Ìlá»Ìbá»Ìlá»Ì. TiÌ aÌwá»n oÌnwoÌran yoÌoÌ siÌ maÌa fá»Ìn omi lu aÌwá»n oluÌdiÌje yiÌiÌ biÌ wá»n ti n ká»rin tiÌ wá»n siÌ n joÌ kiri ojuÌ-poÌpoÌ. NiÌgbaÌ tiÌ aago sá»Ìá»ÌsiÌ baÌ luÌ meÌjiÌlaÌ á»ÌsaÌn, aÌwá»n á»ká»Ì-akáșčÌruÌ tiÌ wá»n kuÌn dáșčÌnu yoÌoÌ báșčÌráșčÌ siÌ niÌ wá»ÌluÌ, tiÌ ariwo âTo-ma-ti. To-ma-ti yoÌoÌ siÌ gba gbogbo afáșčÌfáșčÌ kiÌkankiÌkan. LáșčÌyiÌn naÌaÌ, ni wá»n maÌa rá»Ì aÌgbaÌ oloÌmi, tiÌ gudugbáșčÌ-eÌtoÌ yoÌoÌ siÌ báșčÌráșčÌ. EÌyiÌ ni aÌmiÌ ereÌ-yaÌ fuÌn tiÌtáșčÌ aÌti siÌsá» okoÌ tomato niÌ gbogbo á»ÌnaÌ yoÌoÌwuÌ siÌ áșčni ti oluÌkuÌluÌkuÌ ba dojuÌ ká». á»ta tomato atamaÌtaÌáčŁeÌ á»lá»ÌnaÌ-jiÌáč
jiÌn, á»ta páșčÌkiÌ-n-páșčÌkiÌ, aÌti á»ta koÌjiÌn-koÌ-suÌnmá»Ì. á»ÌnaÌká»naÌ yoÌoÌwuÌ tiÌ o ba yaÌn, niÌgbaÌ tiÌ aÌsiÌkoÌ baÌ fi maÌa toÌ, biÌ iÌwá» yoÌoÌ áčŁe maÌa woÌ (aÌti biÌ ara ráșč áčŁe maÌa riÌ) maÌa yaÌtá»Ì. LáșčÌyiÌn biÌ á»gbá»Ìn iÌáčŁáșčÌjuÌ, wá»n yoÌoÌ fi aÌwá»n sá»ÌkoÌ-sá»ÌkoÌ tiÌ gbogbo ara wá»n ti rin fuÌn tomati siÌláșčÌ kiÌ wá»n maÌa luÌwáșčÌáșčÌ niÌnuÌ pá»tá»pá»Ìtá»Ì tiÌ koÌtiláșčÌ fi ibi kankan já» tomato má»Ì. AÌgbaÌ áșčláșčáșčÌkejiÌ tiÌ wá»n baÌ rá»Ì jaÌsiÌ peÌ aÌkoÌkoÌ giÌdiÌgboÌ-giÌdiÌgboÌ ti pariÌ ni yáșčn. | Entry #21139 — Discuss 0 — Variant: Not specifiednone
Voting points | 1st | 2nd | 3rd |
---|
17 | 3 x4 | 2 x2 | 1 x1 |
- 2 users entered 7 "dislike" tags
- 1 user agreed with "dislikes" (1 total agree)
bá»Ìwá»Ì soÌriÌ ni | Spelling Except one refers back to the source text, one finds it difficult understanding what is being said. | Olayemi Olabenjo No agrees/disagrees | |
koÌ má»Ì | Syntax nkoÌ má»Ì is i don't know. It should be koÌ má»Ì | Olayemi Olabenjo No agrees/disagrees | |
PáșčÌluÌ iÌbáșčÌruÌbojo peÌ fiÌtiÌnaÌ leÌ waÌyeÌ, ni iÌjá»Ìba ba áčŁoÌfin, laÌti diÌn jaÌgiÌdiÌ-jaÌgan aÌjá»ÌduÌn yiÌiÌ kuÌ, ni wá»n baÌ áčŁaÌgbeÌkaláșčÌ oniÌruÌuruÌ oÌfin laÌaÌrin | Spelling This does not translate in full the English text. | Abiodun Adeleye No agrees/disagrees | |
biÌsiÌkoÌ | Spelling This does not translate fireworks as it is a trade name. | Olayemi Olabenjo No agrees/disagrees | |
niÌ tiÌtoriÌ | Mistranslations This should be "nĂtorĂ". "nĂ tĂŹtorĂ" is slang. | Olayemi Olabenjo No agrees/disagrees | |
tomato | Inconsistencies Tomato or tomati? which is the right translation for tomato in Yoruba? I guess it is Tomati. | Olayemi Olabenjo No agrees/disagrees | |
| Tani Simáșčnti ti aká»ká» fateful tomati ti bere si ni La Tomatina Iyika? Awon otito, ko si á»kan o mo. Boya o je ohun egboogi-Franko iáčŁá»táșč, tabi kan Carnival ti o ni jade ninu á»wá». Ni ibamu si awá»n julá» gbajumo ti ikede awá»n itan, nigba ti 1945 Festival Los Gigantes (kan omiran iwe mĂąchĂ© puppet Itoláșčsáșč á»má» ogun), awá»n agbegbe won nwa lati ipele kan brawl lati gba diáșč ninu awá»n akiyesi. Nwá»n sele lori kan Ewebe fun rira nitosi ati ki o bere si hurling pá»n awá»n tomati. L'onlookers ni kopa ti titi ti nmu escalated sinu kan lowo melee ti flying eso. Awá»n instigators nĂ lati san awá»n tomati olĂčtajĂ , sugbon ti ko da awá»n ifasáșčyin diáșč tomati njĂ -ati awá»n ibi ti titun kan atá»wá»dá»wá». NĂbáșčrĂč ohun unruly escalation, alase ti fi leláșč, ihuwasi, ati ki o reinstated kan láșčsáșčsáșč bans ni 1950s. Ni 1951, awá»n agbegbe ti o defied ofin won ewon titi Ă ká»sĂláșč outcry ti a npe ni fun won sĂláșč. Julá» olokiki effrontery si awá»n tomati bans sele ni 1957 nigbati o waye proponents kan Mock tomati isinku ni pipe páșčlu kan ati ki o coffin procession. Láșčhin 1957, agbegbe ijoba pinnu lati fi eerun páșčlu awá»n punches, áčŁeto awá»n ofin kan diáșč ninu ibi, ki o si gba esin naa wacky atá»wá»dá»wá». Tiláșč awá»n tomati ya ile-ipele, ose kan ti festivities yorisi soke si ik showdown. O kan ajoyo ti Buñol kĂĄ patron mimo, awá»n Virgin MĂ rĂĂ ati St Louis Bertrand, páșčlu ita parades, orin, ati ise ina ni joyous Spani njagun. Lati ká» soke ráșč agbara fun awá»n impending brawl, ohun apá»ju paella ti wa ni yoo wa lori Efa ti ogun, showcasing ohun ala Valencian satelaiti ti iresi, onje bi eja, saffron, ati olifi epo. Loni, yi unfettered Festival ni o ni diáșč ninu awá»n odiwon fun ibere. Awá»n oluáčŁeto ti ki jina bi lati cultivate kan pataki orisirisi ti unpalatable tomati o kan fun awá»n iáčŁáșčláșč lododun. Festivities tapa si pipa ni ayika 10 am nigbati awá»n alabaáčŁepá» ije lati ja gba kan ti o wa titi ngbe atop kan greasy polu. Onlookers okun awá»n scramblers páșčlu omi nigba ti orin ati jijo ni ita. Nigbati ijo Belii dasofo káșčfa, oko nla aba ti páșčlu awá»n tomati eerun sinu ilu, nigbati chants ti "Lati-Ma-te, si-Ma-te!" de á»dá» kan crescendo. Nigbana, páșčlu awá»n tita ibá»n ti kan omi Kanonu, awá»n iáčŁáșčláșč nla bere. Ti o ni ina alawá» ewe fun crushing ati gbesita ni gbogbo awá»n tomati-jade ku lodi si elegbe awá»n alabaáčŁepá». Gun ijinna tomati lobbers, ojuami-ĂČfo assassins, ati alabá»de ibiti o kio Asokagba. Ohunkohun ti ilana ráșč, nipasáșč awá»n akoko ti o ni lori, o yoo wo (ki o si lero) ohun ti o yatá». O fere wakati kan nigbamii, tomati-soaked bombers ti wa ni sosi lati mu ninu omi kan ti squishy ita Salsa páșčlu kekere osi resembling kan tomati lati le ri. A keji Kanonu shot awá»n ifihan agbara opin ogun. | Entry #21673 — Discuss 0 — Variant: Not specifiednone
Voting points | 1st | 2nd | 3rd |
---|
5 | 1 x4 | 0 | 1 x1 |
- 1 user entered 1 "dislike" tag
- 3 users agreed with "dislikes" (3 total agrees)
+3 3 Tani Simáșčnti ti aká»ká» fateful tomati ti bere si ni La Tomatina Iyika? Awon otito, ko si á»kan o mo. Boya o je ohun egboogi-Franko iáčŁá»táșč, tabi kan Carnival ti o ni jade ninu á»wá». | Mistranslations Everything about this whole translation is wrong | Oludamilola I. Oyetoyan | |
| Tani Ăł ká»Ìká»Ì ju tĂČmĂĄtĂŹ nĂĄĂ ĂšyĂ tĂ Ăł báșčÌáșčÌráșčÌ ĂŹáčŁá»ÌtáșčÌ ti La Tomatina? ĂtĂtá»Ì ráșč nipĂ© kĂČsĂ áșčni tĂ Ăł má»Ì. BĂłyĂĄ ĂŹáčŁá»ÌtáșčÌ aáčŁĂČdĂŹsĂ Franko ni, tĂ bĂ Ă já»yá»Ì ĂŹwá»Ìde ijĂł Ă ti ilĂč tĂ Ăł áčŁĂšáčŁĂŹ bá»Ì sĂłdĂŹ. LĂĄra ĂšyĂ tĂ Ăł wá»Ìpá»Ì nĂnu ĂŹtĂ n nĂĄĂ , lĂĄkĂłkĂČ ajá»ÌdĂșn 1945 ti Los Gigante ( ĂŹáčŁafihĂ n ĂČmĂŹrĂĄn Ă fi pĂ©pĂ áčŁe), Ă wá»n ĂŹbĂláșčÌ Ć fa asá»Ì lĂĄti lĂš jáșčÌkĂ wá»Ìn fiyĂšsĂ wá»n. Wá»Ìn gĂșnlĂš kĂškĂ© tĂ ĆkĂł ewĂ©báșčÌ nĂ ĂŹtĂČsĂ tĂ wá»Ìn sĂŹ báșčÌráșčÌ sĂnĂ ju tĂČmĂĄtĂŹ pĂpá»Ìn. Ăwá»n olĂčwĂČran kĂłpa nĂnu ráșčÌ tĂ ĂŹwĂ yĂi fi gbĂŹnĂ yĂĄ sĂ jĂju ohun Ăšso ĆlĂĄ. Ăwá»n tĂ Ăł áčŁokunfĂ ĂšyĂ nĂlĂČ lĂĄti san owĂł ĂŹdĂĄpadĂ fĂșn olĂčta tĂČmĂĄtĂŹ, áčŁĂčgbá»Ìn ĂšyĂ kĂČ dĂĄwá»Ì ĂŹjĂč padĂ Ă wá»n ĂŹjĂ tĂČmĂĄtĂŹ dĂșrĂłâĂ ti ĂŹáčŁáșčÌdĂĄ Ă áčŁĂ titun. NĂtorĂ ĂŹbáșčrĂč ĂŹrusĂłkĂš tĂ akĂČle áčŁĂ kĂłso, Ă wá»n alĂĄáčŁáșč pĂĄ lĂĄáčŁáșč, dáșčwá»Ì, wá»Ìn sĂŹ tĂșn áčŁĂ fĂlĂ©láșčÌ orĂáčŁi ĂŹfilá»Ì ĂŹtagbangba nĂ Ă wá»n á»dĂșn 1950. Ni 1951, Ă wá»n ĂŹbĂláșčÌ tĂ Ăł tĂ pĂĄ sĂłfin yĂŹĂ nĂ a tĂŹ má»ÌlĂ© tĂtĂ tĂ Ă wá»n arĂĄ ĂŹlu kĂgbe sĂta fĂșn ĂŹdĂĄsĂláșčÌ wá»n. ĂáčŁĂĄfojĂșdi tĂ Ăł lĂłkĂŹkĂ jĂčlá» sĂ ĂŹfilá»Ì ĂŹtagbangba áčŁáșčláșčÌ nĂ 1957 nĂgbĂ tĂ Ă wá»n olĂșdĂĄsĂláșčÌ áčŁe ĂŹáčŁáșčfáșčÌ ĂŹtĂČkĂș tĂČmĂĄtĂŹ páșčÌlĂș odindi pĂłsĂ Ă ti ĂŹwá»Ìde á»Ìpá»Ì ĂšnĂŹyĂ n. LáșčÌhĂŹn 1957, ĂŹjá»ba ĂŹbĂláșčÌ dáșčwá»Ì, wá»Ìn áčŁe ĂČfin titun, wá»Ìn sĂŹ faramá»Ì Ă áčŁĂ aáčŁiwerĂš yĂĂŹ. BĂ-Ăł-tiláșčÌ-jáșčÌ wĂ pĂ© tĂČmĂĄtĂŹ gba ĂČde kan, á»ÌsáșčÌ kan ajĂČdĂșn áčŁĂČkunfĂ á»já»Ì ĂŹkáșčhĂŹn ĂŹfigagbĂĄga. Ă jáșčÌ Ă já»yá»Ì áșčni mĂmá»Ì alĂĄĂ bĂČ Buñol, MĂ rĂĂ WĂșndĂĂĄ Ă ti áșžni mĂmá»Ì Louis Bertrand, páșčÌlĂș ĂŹwá»Ìde ĂČpĂłnĂ , orin, Ă ti ayáșčyáșč orĂáčŁi inĂĄ jĂjĂł nĂ ĂŹlanĂ Ă já»yá»Ì Ă áčŁĂ arĂĄ SĂpĂĄĂŹn. LĂĄti áčŁĂšâgbĂĄradĂŹ okun ráșč fĂșn asá»Ì tĂ Ć bá»Ì, a ĆáčŁe ĂŹpesĂš oĂșnjáșč Ă rĂ á»Ìtá»Ì onĂráșčsĂŹ nĂ aláșčÌ áčŁĂĄĂĄjĂș á»já»Ì ogun, ĂšyĂ tĂ Ć áčŁĂ fihĂ n ĂŹrĂ ĂkĂłjá»pá»Ì Ă wopá»Ìká»Ì ĂŹráșčsĂŹ, oĂșnjáșč odĂČ, ĂČdĂČdĂł Ă rĂ á»Ìtá»Ì, Ă ti ĂČrĂłrĂł ĂłlĂfĂŹ. LĂłnĂŹ, Ă já»ÌdĂșn Ă ĂŹnĂdinwá»Ìn yĂi nĂ gbĂšndĂ©ke ĂštĂČ. Ăwá»n olĂčgbĂ©kaláșčÌ ti rĂŹn jĂŹnnĂ nĂ gbĂngbin Ă wá»n Ă rĂ á»Ìtá»Ì tĂČmĂĄtĂŹ tĂ kĂČ dĂčn láșčÌnu fĂșn ĂštĂČ á»dá»dĂșn yĂŹĂ nĂŹkan. Ăjá»ÌdĂșn báșčÌráșčÌ nĂ bii agogo máșčÌwĂ ĂČwĂșrá»Ì, nĂgbĂ tĂ Ă wá»n olĂčkĂłpa sĂĄrĂ© lĂĄti mĂș áșčran tĂ a somá»Ì orĂ ĂČpĂł yĂyá»Ì. Ăwá»n olĂčwĂłran tĂș omi sĂ ara Ă wá»n olĂčjĂŹjĂ dĂč nĂgbĂ tĂ wá»Ìn Ć ká»rin páșčÌlĂș ijĂł nĂ ĂČpĂłpĂł. NĂgbĂ tĂ ago ilĂ© ĂŹjá»sĂŹn lĂč lá»ÌsĂ n, Ă wá»n á»ká»Ì tĂ Ăł kĂł tĂČmĂĄtĂŹ wá»ÌâlĂș, nĂgbĂ tĂ ariwo "TĂČ-mĂĄ-tĂŹ, tĂČ-mĂĄ-tĂŹ" dĂ© gĂłĆgĂł. NĂgbĂ nĂĄĂ , páșčÌlĂș ĂŹfomi sâá»ÌkĂČ, ayáșčyáșč gan an báșčÌráșčÌ. ĂyĂ ni Ă Ă mĂŹ fĂșn ĂŹfĂșnpa Ă ti jĂju tĂČmĂĄtĂŹ lĂČdĂŹ sĂ olĂčkĂłpa mĂĂrĂ n. OlĂčjĂč tĂČmĂĄtĂŹ lá»ÌnĂ jĂnjĂn rĂ©rĂ©, apĂ nĂŹa ojĂșkojĂș, Ă ti jĂju Ă ĂŹjĂŹnĂ . ĂyĂkĂ©yĂŹ á»ÌnĂ ĂŹáčŁĂ mĂșlĂČ ráșč, nĂgbĂ tĂ Ă kĂłkĂČ yĂłĂČ parĂ, wĂĄ (nĂmá»ÌlĂĄrĂ ) ti yatá»Ì. LĂ©hĂŹn bii wĂĄkĂ tĂ kan, Ă wá»n olĂčju Ă dĂł olĂłrĂł tĂ Ăł rin páșčÌlĂș tĂČmĂĄtĂŹ laĂłfi sĂláșčÌ lĂĄti áčŁerĂ© nĂnu ĂČpĂłpĂł ĂšrojĂ tĂČmĂĄtĂŹ tĂ Ăł rá»Ì dáșčÌmĂčdáșčÌmĂč páșčÌlĂș ohun kĂ©rĂ©je tĂ Ăł já» tĂČmĂĄtĂŹ tĂ a lĂšrĂ. ĂgbĂĄ ĂŹkejĂŹ tĂ a yĂŹn áčŁĂ fihĂ n ĂČpin ogun. | Entry #18826 — Discuss 0 — Variant: Not specifiednone
Voting points | 1st | 2nd | 3rd |
---|
5 | 0 | 1 x2 | 3 x1 |
- 2 users entered 8 "dislike" tags
ipĂ© | Grammar errors These are separate words. It should read "ni pĂ© kĂČ sĂ" | Olayemi Olabenjo No agrees/disagrees | |
kĂškĂ© | Spelling This word is not properly spelt; it is káșčÌkáșčÌ | Olayemi Olabenjo No agrees/disagrees | |
owĂł ĂŹdĂĄpadĂ | Spelling Word used âdoes not fâully portrâay the meaâning in Enâglish. | Abiodun Adeleye No agrees/disagrees | |
NĂtorĂ ĂŹbáșčrĂč ĂŹrusĂłkĂš tĂ akĂČle áčŁĂ kĂłso, Ă wá»n alĂĄáčŁáșč pĂĄ lĂĄáčŁáșč, dáșčwá»Ì, wá»Ìn sĂŹ tĂșn áčŁĂ fĂlĂ©láșčÌ orĂáčŁi ĂŹfilá»Ì ĂŹtagbangba nĂ Ă wá»n á»dĂșn 1950. | Spelling Something is wrong with the word order that makes its meaning somehow. | Abiodun Adeleye No agrees/disagrees | |
ajĂČdĂșn | Spelling Wrong spelling. It's Ă já»ÌdĂčn. | Olayemi Olabenjo No agrees/disagrees | |
LĂĄti áčŁĂšâgbĂĄradĂŹ | Syntax It's LĂĄti gbĂĄradĂŹ fĂșn... | Olayemi Olabenjo No agrees/disagrees | |
| Taani çni tĂ Ăł ju tĂČmĂĄtĂŹ Ă kökö ĂšyĂ tĂ Ăł bĂȘrĂȘ Ă sĂ tĂČmĂĄtĂŹ jĂjĂč mö ara çni? ĂtĂtö ibĂȘ ni wĂ pe kĂČ sà çni tĂ Ăł leĂš sĂŽ. BĂłyĂĄ Ăł leĂš jĂ« ĂŹdĂŹtĂȘ tako ĂȘyĂ faransĂ© tĂ bĂ ayçyç kan tĂ apĂĄ ĂČ kĂĄ mö ni. GĂ«gĂ« bĂ ĂŹtĂ n kan tĂ Ăł gbajĂș gbajĂ tĂ a gbö se wĂ, nĂ Ă kĂłkĂČ ĂŽdĂșn Losi GĂŹgĂĄntçsĂŹ nĂ ĂŽdĂșn 1945 (nĂ ibi tĂ wön tĂ mĂĄa ngbĂ© ĂČmĂŹrĂĄn dĂŽmĂ tĂ wön fi tĂĄkĂ dĂĄ tĂ wön gĂșn pĂ” se yĂ kĂĄ ĂŹlĂș), Ă wĂŽn ĂŽmĂŽ ĂŹbĂlĂȘ nwĂĄ Ă”nĂ bĂ wön se leĂš pĂ tç rĂČgbĂČdĂŹyĂ n lĂĄĂ rin ĂŹgboro kĂ wön leĂš fi polongo ara wĂŽn. LĂłjijĂŹ ni wön bö sĂ orĂ ĂŽmĂŽlanke kan tĂ Ăł wĂ nĂ ĂŹtĂČsĂ, wön sĂŹ bĂȘrĂȘ sĂ nĂ ju tĂČmĂĄtĂŹ tĂ Ăł ti pön mö ara wĂŽn. ĂwĂŽn olĂčwĂČran tĂ wĂŽn ĂČ mĂŽwö-mçsĂȘ nĂĄĂ fi ara gbĂĄ nĂ bĂȘ tĂtĂ tĂ Ă”rĂ” nĂĄĂ fi di bĂ oĂČ lĂŽ yĂ fĂșn mi, tĂ gbogbo ÚÚyĂ n sĂŹĂ nsĂĄrĂ© sĂłkĂš-sĂłdĂČ nĂgbĂ tĂ Ăšso tĂČmĂĄtĂŹ nfĂČ kiri sĂhĂŻn-sĂłhĂŒn. ĂwĂŽn tĂ wön bĂȘrĂȘ Ă”rĂ n yĂ nĂ lĂĄti san owĂł fĂșn onĂtĂČmĂĄtĂŹ nĂĄĂ , sĂčgbön ĂšyĂ kĂČ dĂĄ a dĂșrĂł pĂ© kĂ ĂŹsĂȘlĂȘ ĂŹjĂ tĂČmĂĄtĂŹ Ăł mĂĄ tĂșn sçlĂȘ mö- bĂ«ĂȘni kĂČ se ĂŹdĂĄdĂșrĂł fĂșn bĂbĂ Ă sĂ tuntun. NĂ ĂŹbĂȘrĂč pĂ© kĂ Ă sĂ yĂŹĂ mĂĄ baĂ pelĂ©ke sĂ i, Ă wĂŽn alĂĄsç se ĂČfin lĂĄkÂșkĂČ kan, wön tĂșn dç ĂŽwö dĂĂȘ lĂĄra ĂČfin nĂĄĂ , lĂ«hĂŹn nĂĄĂ wön tĂșn se onĂrĂșurĂș ĂČfin lĂĄti gbĂ«sĂȘ lĂ© irĂș Ă sĂ kĂĄsĂĄ bĂ«ĂȘ, ĂŹyçn nĂ Ă Ă rin ĂŽdĂșn 1950 sĂ 1959. NĂ ĂŽdĂșn 1951, Ă wĂŽn ĂŽmĂŽ ĂŹbĂlĂȘ tĂ wön rĂș ĂČfin yĂŹ Ă ni wön fi ĂȘwĂ”n jura tĂtĂ di ĂŹgbĂ tĂ Ă wĂŽn arĂĄ ĂŹlu se ĂŹwĂłde ĂŹfĂȘhĂłnĂșhĂ n lĂĄti pĂš fĂșn ĂŹtĂșsĂlĂȘ wĂŽn. ĂgbĂ©sĂȘ akin tĂ Ăł gbajĂș gbajĂ jĂčlĂŽ lĂĄti gbĂ«sĂȘ lĂ© Ă sĂ tĂČmĂĄtĂŹ jĂjĂč mö ara çni ni ĂšyĂ tĂ Ăł wĂĄyĂ© nĂ ĂŽdĂșn 1957 nĂgbĂ tĂ Ă wĂŽn tĂ Ăł se agbĂĄteru ĂČfin nĂĄĂ se ĂštĂČ ĂŹsĂŹnkĂș çlĂ«yĂ fĂșn tĂČmĂĄtĂŹ pĂȘlĂș pĂłsĂ kan, tĂ wön sĂŹ tĂČ löwÔÔwö. LĂ«hĂŹn ĂŽdĂșn 1957, ĂŹjĂŽba ĂŹbĂlĂȘ pinnu lĂĄti wĂĄ gbogbo Ă”nĂ lĂĄti wĂĄ ojĂștĂŒ sĂ ĂŹsĂČro yĂŹĂ, wön gbĂ© ĂČfin bĂi mĂ©lĂČĂł kan kalĂȘ, wĂĄ fi ĂŽgbön fi ara mö Ă sĂ rĂndinrĂndin yĂŹĂ. BĂĂłtilĂȘjĂȘwĂŹpĂš tĂČmĂĄtĂŹ ni wön fi orĂ Ă jĂ”dĂșn yĂŹĂ sĂŽ, onĂrĂșurĂș ĂštĂČ ayĂ”-ĂŽdĂșn tĂ Ăł gba Ă”sĂȘ kan gbĂĄko wön ni won npiyamĂŽ tĂtĂ di ĂŽjö Ă sĂškĂĄgbĂĄ jĂ gĂdĂjĂ gan nĂĄĂ . ĂyĂ jĂ« ayçyç Ă yĂ«sĂ fĂșn pĂĄtrĂĂłnĂŹ mĂmö ti BĂčnĂłlĂŹ, Maria mĂmö Ă ti LĂșwĂŹsĂŹ BĂĄtĂrĂĄndĂŹ mĂmö, pĂȘlĂș ĂŹyankĂĄlĂŒ, orin, Ă ti tĂtan inĂĄ alĂĄrĂ nbarĂ lönĂ tĂ Ăł bĂĄ Ă sĂ SĂpĂĄnĂŹshĂŹ mu. LĂĄti gbaradĂŹ fĂșn rĂČgbĂČdĂŹyĂ n tĂ Ăł seĂ©se kĂ Ăł sçlĂȘ, oĂșnjç ĂŹsĂȘnbĂĄyĂ© tĂ wĂŽn ĂŸpĂ© ni pĂ Ă«lĂ , ĂłrisĂŹĂ oĂșnjç kan tĂ Ăł wöpĂ” nĂ agbĂšgbĂš FĂ lĂ«nsĂŹĂ tĂ wĂŽn fi ĂŹrçsĂŹ, çran, çja Ă ti ewĂ©bĂȘ pĂšse rĂȘ, ni wĂŽn nhĂĄ fĂșn Ă wĂŽn akĂłpa lĂĄti jç nĂ ĂŽjö tĂ ayçyç onĂrĂČgbĂČdĂŹyĂ n yĂŹĂ bĂĄ ku Ă”la. LĂłnĂŹĂ, ĂŽdĂșn yĂŻ tĂ kĂČ ti nĂ ijĂ nu tĂ«lĂȘ rĂ ti wĂ lĂ©tĂČlĂ©tĂČ bĂĄyĂŹĂ. ĂwĂŽn tĂ nse ĂštĂČ ayçyç yĂŹĂ ti wĂĄ sĂ© dĂ©bi pĂ© wön ngbin onĂrĂșurĂș tĂČmĂĄtĂŹ tĂ kĂČ seĂ© jç fĂșn ayçyç ĂŽlödĂŽĂŽdĂșn yĂŹĂ lĂĄsĂĄn. Ayçyç nbĂȘrĂȘ nĂ dĂ©Ă©dĂ© aago mĂ«wĂ ĂĄ ĂČwĂșrĂ” nĂgbĂ tĂ Ă wĂŽn akĂłpa yĂłĂČ mĂĄa sĂĄrĂ© lĂĄti gbĂĄ çsĂȘ çlĂ«dĂȘ tĂ wön so mö ara ĂČpĂł kan tĂ nyĂ” mĂș. ĂwĂŽn olĂčwĂČran ĂĄ mĂĄa tç omi sĂ wĂŽn lĂĄra bĂ wön se nlĂ kĂ kĂ lĂĄti gun ĂČpĂł yĂŹ Ă, tĂ wön si nkĂŽrin, tĂ wön njĂł lĂłjĂș pĂłpĂł. NĂgbĂ tĂ aago söÔsĂŹ bĂĄ lu ti Ă”sĂĄn, Ă wĂŽn ĂŽkĂ” akĂ«rĂč tĂ Ăł kĂșn fĂșn tĂČmĂĄtĂŹ ĂĄ wĂ”lĂș, bĂ«ĂȘ ni ariwo âTĂČ-mĂĄ-tĂŹ, tĂČ-mĂĄ-tĂŹâ ĂĄ gba gbogbo agbĂšgbĂš kan. LĂ«yĂŹn ĂšyĂ pĂȘlĂș yĂnyin ĂŹbĂŽn olĂłmi, ojĂșlĂłwĂł ayçyç bĂȘrĂȘ nĂ pçrçwu. ĂyĂ ni ĂŹbĂȘrĂȘ fĂfö Ă ti jĂju tĂČmĂĄtĂŹ mĂŽ ara çni. ĂwĂŽn tĂ Ăł jĂ« pĂ© lĂĄti ĂČkÚÚrĂš ni wön ti nju tĂČmĂĄtĂŹ ti wĂŽn, Ă wĂŽn tĂ wön nà çni tĂ wön fi ti wĂŽn sĂčn, Ă ti Ă wĂŽn tĂ wĂŽn kĂČ jĂŹnnĂ pĂșpĂ” sĂ ojĂș agbo, gbogbo wĂŽn nĂĄĂ ni wön sĂĄĂ nju tĂČmĂĄtĂŹ bĂ wön se fĂ«. ĂyĂkĂ©yĂŹĂ Ă”nĂ tĂ o leĂš gbĂ mĂĄa jĂč Ăș, nĂgbĂ tĂ yĂłĂČ bĂĄ fi di ĂČpin ohun gbogbo, wĂ ĂĄ wo ara rç (Ăł sĂŹ mö lĂĄra) pĂ© o ti yĂ tĂ”. LĂ«yĂŹn nkan bĂ wĂĄkĂ tĂ kan Ăł dĂn dĂĂȘ, Ăł ku kĂ Ă wĂŽn tĂ omi tĂČmĂĄtĂŹ ti mĂč dĂčndĂčndĂčn mĂĄa serĂ© nĂnĂș agbami tĂČmĂĄtĂŹ tĂ Ăł ti rĂ” dĂČmĂč-dĂČmĂč tĂ Ăł kĂșn lĂȘ, tĂ ĂČ tiĂȘ sĂŹ jĂŽ tĂČmĂĄtĂŹ mö. YĂnyĂn ĂŹbĂŽn lĂ«ĂȘkejĂŹ ni Ăł nse Ă mĂŹn ĂČpin ĂŹjĂ gbĂčdĂč nĂĄĂ . | Entry #21047 — Discuss 0 — Variant: Not specifiednone
Voting points | 1st | 2nd | 3rd |
---|
0 | 0 | 0 | 0 |
- 1 user entered 1 "dislike" tag
- 1 user agreed with "dislikes" (1 total agree)
+1 1 Taani çni tĂ Ăł ju tĂČmĂĄtĂŹ Ă kökö ĂšyĂ tĂ Ăł bĂȘrĂȘ Ă sĂ tĂČmĂĄtĂŹ jĂjĂč mö ara çni? ĂtĂtö ibĂȘ ni wĂ pe kĂČ sà çni tĂ Ăł leĂš sĂŽ | Spelling There is a problem with the tonal marks used. | Abiodun Adeleye | |
| | | | | X Sign in to your ProZ.com account... | | | | | | ProZ.com translation contestsProZ.com translation contests offer a fun way to take a break from your normal routine while testing and honing your skills with fellow translators.
ProZ.com Translation Contests. Patent pending. |